text
stringlengths
9
354
label
int64
0
1
Ìwọ tí o wà lẹ́nu iṣẹ́ ni mo bá lọ̀rọ̀. Iṣẹ́ẹ̀ rẹ ò ní dojú ìjà kọ ọ́ lọ́dún yìí, wà á jèrè, wà á fi erèé jẹ̀kọ. Ẹ máa yá'ṣẹ́ o!
1
RT @user: @user Ooto oro ni jare, Alakowe. A fi Olorun so emi gbogbo wa ni o.
1
Èmi kì í ṣe onímẹ̀ẹ́lẹ́, ni mo ṣe mú iṣẹ́ àgbẹ̀ mọ́ iṣẹ́ oṣù. Àgbàdo, ewédú àti ẹ̀fọ́ ti ń gbéra ńlẹ̀. @user #NigeriansAreNotLazy #Yoruba https://t.co/24HB0BdjPu
1
RT @user: @user A kú ìsinmi òní o
1
@user e se o bee ni yoo ri fun eyin naa
1
RT @user: @user: E ma binu, mi o se a foju o. Mo kan se efe ni.
1
3. Rántí wípé, ẹní bá fẹ́ jẹ oyin inú àpáta ò gbọdọ̀ wo ẹnu àáké. Ìwọ ṣá ma ṣe ohun o mọ̀ ọ́ ṣe lọ, ire ń bọ̀ níkòpẹ́. #Abameta
1
Mo ti gba ọ̀nà ìyè yìí ná ... #Yoruba
1
RT @user: """"""""@user: Ó tó gẹ́, ọwọ́ ń ro mi, oorun ń kùn mí pẹ̀lú. Ọ̀kọ̀ọ̀kan la óò jìí o"""""""" amin o.
1
@user Yorùbá ní, ọmọ tí ó bá ṣípá ni ìyá ẹ̀ ń gbé. Níwọ̀n ìgbà tí ẹ bá ti pinu pé ẹ fẹ́ kọ́ ọ, kò s'éwu lóko àfi gìrì àparò. Mo ṣe tán.
1
Mo fe di Ogun! Mo fe di Ogbon! Iriri Aiye>>> Oloogbe Audu Abubakar Sun Ree o! ma je okun, ma je ekolo, ohun ti won ba je ljule orun ni jo je
1
RT @user: Eyin temi eku ojumo, emi eyan yin ogbeni Taofeek Omo Gawat Omo bibu ilu eko Ni Massey, Eko mi eko Ilé 🏡, eko Oni baje #Tweet…
1
RT @user: Mo ki gbo gbo awa omo Karo Oji ri, ki apejo #TweetYoruba ko san wa si ire, owo, omo, alafia. Ki afefe ife, afefe ayo o fe s…
1
Rere ló pé ìkà ò pé. Ẹ jẹ́ ká ṣe rere o.
1
Aṣọ wa ò ní fàya o, àwọn tí kòì tí ì ní aṣọ láyé yóò ti ọwọ́ àlà bọ osùn fi pa ọmọ lára láṣẹ Èdùmàrè. #AyajoOjoAwonEwe #Yoruba
1
@user mo ti ntele yin bayii inu mi yoo dun ti e ba tele mi pada
1
Ọ̀RỌ̀ ÌṢÍTÍ WA T'ÒNÍ: ÌMỌRÍRÌ (Our admonition for today: Appreciation) #yoruba #oroisiti #admonition #imoran #appreciation #gratitude #thankyou #letuslearn #lestweforget #yorubaculture #yorubasindiaspora… https://t.co/BmMaoMGrYs
1
ÌTÚNRATÒ A ti pé oṣù mọ́kànlá lórí Twitter, tí a sì dúpẹ́ fún àtìlẹ́hìn yín. Ẹ jọ̀wọ́, a ma fẹ́ láti mọ bí ẹ ti ṣe rí ìrìn yín pẹ̀lú wa sí, nípa; bí ẹ ṣe rí àwọn kíkọ wa, ibi tí a kù sìí. Ati wípé, ọ̀nà tí a tún ṣe lè gbà fún yín ní ìrírí tó jọjú
1
Òróró àràmàndà inúu rẹ̀ pàápàá wúlò fójú tójú yíò ma ríran kedere á tún máa mú ara dán bíi wúra. #Yoruba #asala
1
A ò ní ṣe é TÌ, a ò ní di ÀWÁTÌ t'ilé t'ẹbí t'ọ̀rẹ́ t'ará, ojú ò sì ní í TÌ wá lọ́lá ònìí tí í ṣe ọjọ́ ẸTÌ. #Iwure #Yoruba #Eti #Friday
1
Àlùpàyídà paradà, b'éégún bá wọnú ẹ̀kú a pohùndà; b'ẹ́dìẹ gorí àba a pohùndà. Ewé #alupayida dára fún àrùn ọkàn. #Yoruba #herbs #Osanyin https://t.co/hnA9fMTRIS
1
RT @user: #TweetInYoruba 🎵 E kilo fomode ko ma rin nipado, ko ma sesi fara gbogidan lojiji. Igboran san jebo ruro... 🎵 ~ King Sunday Ade…
1
Bí ìgbà-á bá ń gbáni, ká máa rọ́jú, nítorí ìgbà sì ń padà bọ̀, tí ìgbà yóò tún gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ ìyà. #EsinOro🐎 #Yoruba #COVID19
1
Àwọn tọ́n le fi omi pamọ́ sára bí igi ọ̀pẹ. Tó bá di ọ̀la n ó dé ibi tí wọ́n ń pè ní """"""""Ilẹ̀ Ẹlẹ́gbẹ̀rún Igi Ọ̀pẹ"""""""". Lágbára Ọlọ́run.
1
Ònìí kọ́ la ti ń lo ògógóró tí a rẹ onírúirú ewé sí fi to àgbo fún ìwòsàn ọmọ aráyé tí ewé sì ń jẹ́ ẹ̀! #Ogogoro #Yoruba #Agbo
1
A lè ti gbàgbé, àmọ́ ẹ jẹ́ n rán an yí létí pé iṣẹ́ àgbẹ̀ niṣẹ́ ilẹ̀ wà, ẹ jẹ́ a ṣe é, fún ànfààní wa ni. #IseAgbeNiseIleeWa
1
RT @user: Hmm!Oba aseyi owu, """"""""@user: Ọlọ́run tóbi lọ́ba. Ibi tí àwọn kan ti nlàágùn nítorí ooru ni àwa kan ngbọ̀n tìtììtì ...
1
A #Yoruba #Poem - Ise Logun Ise ~ With #English Translation - #xpino #SCHOLARS https://t.co/NNtbyKoJi3 #Education #Nigeria #Lagos
1
Ojúmọ́ kan kìí mọ́n, àyàfi àṣẹ Olódùmarè. Ẹnìkan kìí dìde lórí ìtẹ́ bí kìí ṣe ore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run. #Ekaaaro #Olorunseun
1
RT @user: Asẹ̀dá mójúbà, arayé mójúbà ẹ jẹ ó se se fún wá l'óní o..... Ẹ káàárọ̀
1
RT @user: Amin o! O wu mi lori pupo. https://t.co/lb1VRiRN8F
1
Mo kí dede ọmọ Ẹ̀gbá mọlíṣàbí #Abeokuta #Ogun
1
@user ose yi a tura ko ni le Koko Mo mi #yoruba
1
Ọjọ́ 1-4-2015, ọ̀gágun Muhammadu Buhari t'ó ti fìgbà kan rí jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ #Nigeria ní ọdún 1983 ni ó jáwé olúborí ìbò ààrẹ. #NigeriaTitun
1
Òní ni Àyájọ́ Ọjọ́ Ìtumọ̀ Àgbáyé. Gbogbo wa ní @user àti ẹ̀ka rẹ̀, @user ń kí àwọn tí ó ń tú ìmọ̀ ìròyìn àgbáyé sí onírúurú èdè abínibí kú iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ń ṣe. 💚 #ITD #ITD2019 #WeAreIndigenous #Language https://t.co/1R6HvvQuM9
1
RT @user: Ase o""""""""@user: A kú ọrọ̀ Ajé àt'òórọ̀ o. Á yẹ wá kalẹ́ o.""""""""
1
@user Àdúrà ti gbà! Ẹṣeun o --> @user :)) http://t.co/dmK8UwX5
1
Ẹ ṣé járe, ẹ bá wa bèèrè #20billion owóo wa """"""""@user: #WhereIsOurMoney?! (@user NNPC Building) http://t.co/sdZdVrLkOV"""""""" #WeWantTheTruth
1
Ẹ káàárọ̀ o, ẹ kú ìsimi o :) #yoruba
1
Àḿbọ̀, rí i dájú wípé iléeṣẹ́ @user ṣeṣẹ́ àtúnṣe sí àwọn òpó wọ̀nyí bí ó bá bàjẹ́. Ìtesíwájú Èkó l'ó jẹ wá l'ógún! @user
1
Irin-iṣẹ́ wa ò ní dojú ìjà kọ wá. Mọ́tò wa ò ní f'orí sọgi, ọkọ̀ọ wa ò ní tàkítí. Búburú kan ò ní wa á ṣe.
1
Tóò, Yoòbá ní ẹnu onípọ̀n la ti ń gbọ́ pọ̀ọ́un, òun lẹ ti gbọ́ yẹn lẹ́nu @user nípa ọ̀rọ̀ #LASU. Nǹkan yóò ṣì dára ni wọ́n fi yé wa
1
RT @user: @user @user ☺ esanu Alufaa Oo°˚˚˚°! Ise iranti ona agbelebu ni won se Oo°˚˚˚°!
1
@user ti pèsè ọkọ̀ ẹlẹ́rọ a-yẹ-omi-wò tí yóò ma lọ kiri láti bẹ ilé-iṣẹ́ olómi wò bóya omi wọn mọ fún mímu. #Nafdac
1
♪ Gbà wá lọ́wọ́ ikú òjijì o. Olúwa! Gbà wá lọ́wọ́ ewu mótò. Gbà wá lọ́wọ́ ikú òjijì o. Olúwa! Gbà wá lọ́wọ́ ewu cycle o! ♪
1
♫ ♪ Ọmọ ní í sìnsìnkú ni sìn! Ọmọniyì. Ọmọ ni idẹ ♫ ♪ #Children'sday #Nigeria #ChildRightsAct
1
#Yoruba Bo: Bi O Ba Nidi Obinrin Ki Je Ikumolu Madam No go Control Our Family
1
Ṣẹ̀ṣẹ̀ l'ọmọdé ńyọ̀ mẹ́yẹ, oṣó àtàjẹ́ ayé, ẹ yọ̀ mọ́ mi. Gẹ̀gẹ̀ ni à ń gbé ọmọ tuntun. Kọ́mọ aráyé ó máa gbé mi gẹ̀gẹ̀ lọ́dún tuntun.#Iwure
1
@user Òkìkí yín ti kàn dé ìlú wa o. Gbogbo èèyàn ń sọ̀rọ̀ nípa òyìnbó tó gbó ìjìlẹ̀ Yorùbá lẹ́hìn ètò tí ẹ ṣe lórí asọ̀rọ̀mágbèsì :)
1
Kíni ẹ̀yin fi ṣe oújẹ àárọ̀? Ọkà bàbà ni tèmi, àti ẹja'dín. Ẹ bá wa 're o. #ounje #aaro #Yoruba http://t.co/RltiHrt0eq
1
Àbá 3 - Ìyá, bàbá ló yẹ ó bá ọmọ wí, ká jọ p'ẹnu, apá òsì pọ̀ bá èwe wí bí wọ́n bá ṣàṣìṣe. Kí a sì jọ fọwọ́ ọ̀tún fà wọ́n mọ́ra. #Abameta
1
RT @user: Kò sí ohun tó ní ìbẹ̀rẹ̀ tí kò ní lópin. / There is nothing that has a beginning that won't have an ending. [Keep hope…
1
E okun o, se ajirebi? Adekunle ni emi nje, Omo bibi ilu Mopa ni ipile kogi ni emi se. Ponbele Omo Karo ojire le mi se. Ire o.#TweetinYoruba
1
RT @user: @user eseun gan. A ki yin fun akitiyan yin. Awa na o ni sere legbe peturolu rara.
1
Greeting for Situations This will be splitted into two; Positive and Negative Positive: 1. Someone graduated or won a contract, say things like: Ẹ kú oríire Báyìí báyìí làá máa rí Èdùmàrè á ṣe é níbẹ̀rẹ̀ oore Ẹ̀ ẹ́ fi ṣe nǹkan ire Ẹ ò ní fèyí ṣàṣemọ 5a
1
Wọ́n ní tí adìẹ bá nfẹsẹ̀ halẹ̀ ire ló nwá. Ire Olódùmarè ni fún gbogbowa o. #ekaaro
1
láti pẹ̀tù sí àwọn olórí ogun wọ̀nyìí lọ́kàn, láti jẹ́ kí ìsinmi jọba, kí wọ́n sì fi ọkàn sin Ọba wọn. Ọba kò lè wá sí ìpàdé náà. Ṣùgbọ́n, ó rán Ìlàrí rẹ̀ lọ sí ìpàdé náà. Lẹ́yìn ìfọ̀rọ̀jomiọ̀rọ̀, àwọn olórí ogun gbà láti d'áwọ́ ìjà dúró. Tí wọ́n gbà láti
1
RT @user: Ki Oluwa pa ona mo! """"""""@user: Ẹ kú ojúmọ́ o. Ìrìnàjò la wà. Ọba jẹ́ ká gúnlẹ̀ láyọ̀ o. #ekaaaro #irinajo http://t ...
1
RT @user: Beeni o,TGIF la n pe RT @user: Ṣé òpin-ọ̀sẹ̀ bá gbogbowa láyọ̀? Ayẹyẹ lóríṣìíríṣìí tí iṣẹ́ bá parí àbí? :)
1
Bí ẹ̀mí bá sì wà, ìrètí ń bẹ. Ọ̀báńjígì gba ọpẹ́ẹ̀ mi, modúpẹ́. #yobamoodua
1
RT @user: Elédùmarè Ọba Atẹ́nílẹ́gẹ́lẹ́gẹ́-fi-orí-ṣe-agbeji-ẹni, mo ké pè Ọ́ ní òórọ̀ yìí, kí O máà ṣaláyì jẹ́ mi. Gbé orí mi sókè. Mú…
1
Mi o fe ki ajo LASTMA ati VIO ni awon araalu Eko lara"""" Ambode@user
1
Fi ìṣẹ́ rẹ yangàn nínú Jọ́nà Lítírésọ̀ Yorùbá —àkọ́kọ́ irú ẹ̀ ní Nàìjíríà. Wo línkì yín àlàyé ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. https://t.co/WiQmGKjvoW #Nigeria #Yoruba #Literature
1
@user: @user Aku ojumo oni o. Oni a san wa ju ana lo lase Edumare.""""Àṣẹ o! :) #yoruba
1
@user @user @user Kòṣééfowórà ni ìyá jẹ́. Wúrà iyebíye. Ọlọ́run á dá wọn sí o.
1
Okan mi nso ede ife!(my heart speaks the language of love) #Yoruba #seekingGodparent #IfaIsLife #Modupe #Achè https://t.co/gXqi30a4R1
1
Gbogbo ojo l'o ye ko je #Tweetinyoruba O se dandan ki a gbe ede ati asa wa laaruge
1
@user mo ti n tele yii bayii ki e jowo ki e tele mi pada
1
RT @user: Eyin ara oke oya, e'o ni binu siwa ni ooo. Asa ati ede wa la'n gbe laaruge. #TweetYoruba
1
RT @user: @user A dúpé. Isé Ni ó mú mi mólè. E kú ísé. Inú mi dùn pé open ìmò ma túnbò fún wa ni ònà ti a ma fi gbé Yorùbá ga.
1
@user @user @user @user @user @user @user @user @user Ẹ kú iṣẹ́ náà, Olódùmarè yó tì yín lẹ́yìn.
1
@user Ó dẹ̀ máa fit yín gan o😀
1
RT @user: Ekaaro o , oruko mi ni Olasiji Morakinyo Obatomi. Omo bibi ilu Kabba ni mi, ni ipinle Kogi. Omo Nigeria rere ni mi. #TweetInYo…
1
RT @user: """"""""Iya ni wura iyebiye ti a ko le f'owo ra"""""""" is a popular #Yoruba saying that means 'A mother is a priceless gold (gem) that…
1
Yoruba omo Karo O ji ire! Eje ki a ronu jinle o! Ose wa je wipe igba ti Aare GEJ fe bere ipolongo ibo ni #BokoHaram wa gbo oro si lenu?
1
Ètò yìí kò ní fi àyè gba ọmọ ilé-ìwé láti máa fi àkókò sòfò lásìkò ìsinmi.
1
Nkan nbọ̀ wá dára ní #Nigeria, Ẹ má sọ ìrètí nù.
1
Aarẹ @user ni awọn akẹkọ Dapchi yoo gba itusilẹ. Ẹ gba ijọba ni imọran lori ọna ti wọn le gba tete ri awọn ọmọ naa gba pada.https://t.co/HEbcnxJcBr
1
6. Ẹní, màá máa ní Èjì, ireè mi yóò dèjì, Ẹ̀ta, irúgbìn-ìn mi yó ta Ẹ̀rin, ẹkún-un mi yóò dẹ̀rín Àrún, mi ò ní kú, mi ò ní rùn Ẹ̀fà, n ò ní __ á tì #Ibeere #Yoruba
1
@user @user @user Pẹ́pẹ́yẹ kì í kú sómi ayé, níṣe ló ń f'omi ṣeré, wà á wẹ̀kun ayé já. Wà á dàgbà, wà á dògbó. Kú ìkádún o!
1
Ẹ̀yìn ìgbà tí wọ́n fi ìmọ̀ ṣe ti obìnrin ni ohun gbogbo bẹ̀rẹ̀ sí í gún régé fún wọn n'Ífẹ̀ , iyán-an wọn kò lẹ́mọ́, ọkà-a wọn kò díkókó. #IWD2018 #IWD #IWD2018NG #Yoruba
1
RT @user: @user 🇳🇬🇨🇫🌍Ashura ni iṣọtẹ ti olododo ati ominira pẹlu nọmba kekere, igbagbọ ati ifẹ nla si awọn alade aafin ati aw…
1
RT @user: Amin Ase Eledumare!!! """"""""@user: Ẹ ká alẹ́ o. A ò ní ráburú lọ́dún tuntun o.""""""""
1
RT @user: @user adupe o alaafia ni a wa e ku ijo meta o
1
Àbẹ̀kẹ́ mi, jọ̀wọ́; gbà fún mi Mi ò ṣakọ́ mi ò sì gbéra ga ẹ̀bẹ̀, ni mò ń bẹ̀ fún ìfẹ́ rẹ. #love #poetry #Yoruba #ValentinesDay cc @user @user @user
1
@user A kìí dúpẹ́ ara ẹni o jàre ọ̀rẹ́ mi.
1
Ẹ mà kú ojúmọ́ọ̀! Ṣé dáadáa la jí? Ara ò le bí?
1
@user bàbá ìbejì, t'ọ́jú àwọn èjìrẹ́, ọmọ méjì àwọn alárísìkí ọmọ. Wíníwíní l'ójú orogún èjìwọ̀rọ̀ l'ójú ìyá 'ẹ̀
1
Kudos to you and the team at the forefront sir. Ẹnu ọpẹ́ wa ò ní kan o. Ẹ̀yin èèyàn wa, ẹ gbìyànjú láti túbọ̀ fìdí mọ́lé díẹ̀ sí i. Together we will #FightCovid19 https://t.co/8w7JARxDZV
1
Ọ̀rúnmìlà ṣe báwọn awó ti wí, àwọn Àjẹ́ ò sì rí i gbé ṣe, ó lọ ‘re, ó bọ̀ re. #Gelede #Yoruba
1
RT @user: Gbogbo ohun ti o to, nbo wa seku""""""""@user: Fija folorun ja , ko fowo leran ........ O ku di e....""""""""
1
Mo kí ẹ̀yin arábìrin wa tí ẹ di ṣùkú lérí. Mo kí ẹ̀yin tí ẹ di àṣáńpatẹ́ náà. Mo kí ẹ̀yin arákùnrin wa náà tí ẹ ń dirun ní ìlànà ìgbàlódé.
1
👊Wà á gbayì!!! https://t.co/3PscPQXOTi
1
jíjí tí a jí lónìí, Ọlọ́run ọba ni. Nítorípé ojúmọ́ kan kìí mọ́ àyàfí àṣẹ Olódùmarè. #ekaaro
1
RT @user: Òótọ́ korò, ṣùgbọ́n bí a bá gbé itọ́ ọ rẹ̀ mì, a máa ṣe ara lóore. / Truth is bitter, but if it can be swallowed, it i…
1
@user Ọjọ́kan pẹ̀lú. ẹṣeun ọ̀ná pọ̀ ni o. ẹkú aájò wa náà.
1
@user . A sese gbadun oro iyanju yin pelu Ilan ninu awain Agba osere ori itage wa, Antar Laniyan. E ku igbega nipa: Ase, Ise ati oun ini awa omo Yoruba. Thank you for preserving #Yoruba #culture, #heritage and #tradition. We shall see you on #stage one day.
1
OODUA HERITAGE INTERNATIONAL ORGANIZATION OYOSTATE BRANCH MEMBERS ... OODUA HERITAGE!!! OMOLUABI NI WA OOOO #yoruba #nigeria #america #scotland #england #france #Egypt #southafrica #mexico #ghana #spain #brazil… https://t.co/7wB4JeVeT2
1
Ewé Ọlá rè é. A máa ń lò ó láti fi wo àrùn àtọ̀sí, ẹ̀fọ́rí àti fún ikọ́. Ó sì ń mú ọgbẹ́ sàn kíá. #Yoruba #herbs https://t.co/dR9nm4Jc6A
1
Or'-ofe 'yanu Jesu ko l' egbe . . . O jin ju ti omi okun lo . . . O ga ju oke lo, o dan ju oorun lo Ore-ofe naa si to fun mi O ju gbogbo aisododo mi lo O ju gbogbo 'tiju ese mi E ba mi yin oruko nla ti Jesu, yin Oluwa #Yoruba #HymnFriday
1