[ { "question": "Ìlú wó ni àwọn ènìyàn péjọ sí?", "a": "Ayépé", "b": "Ìbídàpọ̀", "c": "Sòǹdókò", "d": "Ajégúnlẹ̀", "answerKey": "D", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọjá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "[MASK] ni ó joyè nítorí akitiyan rẹ̀ lóri ètò ẹ̀kọ́", "a": "Adúlójù", "b": "Adédùntán", "c": "Tàlàbí", "d": "Ọládélé", "answerKey": "B", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọjá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Àkókò wo ni olè yìí jà?", "a": "Òru", "b": "Àárọ̀", "c": "ìrọ̀lẹ́", "d": "ìdájí", "answerKey": "A", "context": "Àgbẹ̀ pàtàkì ni Oyèjídé ní agbègbè ìbọ́ṣẹ́. Kì í gbin kòkó, bẹ́ẹ̀ ni kì í gbin ọ̀gẹ̀dẹ̀. Ohun tí ó fi ta àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ yọ ni oko àlọ̀ tí ó ń dá. A máa tó ẹgbàá mẹ́rin. Ó máa ń gbin ewùrà díè ṣùgbọ́n èsúrú kì í pọ̀ púpọ̀. Yàtọ̀ si pé ó jé àgbẹ̀, ó tún gbówọ́. Lára àwọn tí ó bà a pààlà ni Àdìsá, Dérìn. Àrẹ̀mú àti Sùúrù. Ọ̀gbìn àgbàdo ni ti Àdìsá, Dérìn a máa dáko rodo; Àrẹ̀mú àti Sùúrù sì gbádùn gbágùúdá àti ilá ní tiwọn.\n\nOlè a máa jà púpọ̀ ní agbègbè yìí. Púpọ̀ nínú àwọn àgbẹ̀ l̀bọ́ṣẹ ti dọdẹ àwọn olè náà títí ṣùgbọ́n pàbó ló já sí. Ọjọó tí ọwọ́ pálábá olè kan máa ségi, oko Oyèjídé ni ó lọ. Lẹ́yìn tí ó tí palẹ̀ oko mọ́ láàjìn, ó gbé ẹrù; ó fẹ́ máa lọ. Bí ó ti gbé ẹrù karí́ ni ó bẹ̀rẹ̀ sí pòòyì lójú kan náà, bẹ́ẹ̀ ni ẹrù kò ṣée sọ̀. Ibẹ̀ ni ilè mọ bá olórò tí àwọn olóko dé bá a; wọ́n sì mú un lọ sí ilé baálẹ̀.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Aṣẹ̀dá ni [MASK]", "a": "Sòǹdókò", "b": "Àyìndé", "c": "Títí", "d": "Jèrùgbé", "answerKey": "A", "context": "Lẹ́yìn tí Kọ́lá àti Jèrùgbé ti fi ara mọ́ àwọn ènìyàn wọn fún ìgbà díẹ̀, wọ́n mú ṣòkòtò bọ́ láti lọ pe ẹni tí yóò fi irun ajá ṣe òògùn owó fún wọn. Iṣẹ́ onítibí ni láti ṣe ẹ̀dà. Ibi tí ó ń gbé jìnnà sí Ẹrè. Kò sí ọ̀nà méjì tí ó dé ìlú náà jù ojú omi lọ lásìkò tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí. Ọkọ̀ ojú omi niwọn ní láti dé ibẹ̀. Níwọ̀n ìgbà tí ó sì jẹ́ ọ̀pá àti òbèlè niwọn fi ń wa ọkọ̀, ó gbà wọ́n ní àkókò díẹ̀. Kọ́lá rọ ìyá rẹ̀ láti fún un ní owó díẹ̀ tí ó nílò fún ìrìn àjò yìí.\n\nÒòrùn ti wọ̀ kí àwọn ènìyàn yìí tó 'mú ọ̀nà wọn pọ̀n. Wọ́n jẹun jẹun yó, wọ́n sì gbé àtùpà amọ̀, okùn, àṣọ àti ọ̀pá sínú ọkọ̀ láti fi ta ìgbòkùn. Ọkọ̀ kékeré tí l̀yá Akin fi máa ń ra ẹja ni wọ́n wọ̀. Akin jókòó sí ẹ̀yìn, Kọ́lá wà ní iwájú. Àyìndé sì lé téé sí orí tẹ́ba ní àárin. Kí wọ́n tó wo ọkọ̀ rẹ̀. Títí fi àdúrà sin Akin àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀. Àyìndé kò wọ ọkọ̀ rí bẹ́ẹ̀ ni kò mọ̀ ọ́n wẹ̀, kò lè mòòkùn nínú omi kí á má sọ nípa odò ńlá tí ó na ìyẹ́ láti ìsálú dé Ẹrẹ̀, ṣùgbọ́n kò jáyà. Ọ̀kan rẹ̀ balẹ̀ pé bí ó bá di bákan, àwọn ọ̀rẹ́ òun yóò gba òun là. llẹ̀ ti ṣú kí ọkọ̀ tó kúrò ní èbúté, Akin ni ó sì ń darí ọkọ̀. Iwájú ọkọ̀ niwọ́n gbé àtùpà sí láti máa ríran. Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìbùsọ̀ mẹ́tàlá, wọ́n yà sí èbúté Ṣabọ́jọ láti sùn.\n\nNígbà tí ilẹ̀ mọ́, gbogbo ilẹ̀ ni ó kún fún yànmùyánmú, wọ́n ti yó, agbèdu wọn pọ́n dòmùdòmù bí ẹ̀yìn ìmọ̀kọ̀. Gbogbo ará àwọn arìnrìn-àjò wá rí pàtipàti. Wọ́n tu ọkọ̀ títí tí ilẹ̀ fi ṣú ní ọjọ́ kejì, ṣùgbọ́n wọ́n dé ibi tí wọ́n ń lọ. Wọ́n ìbá tẹ̀síwájú ṣùgbọ́n epotó wà nínú fìtílà ti gbẹ. Èyí ló mú kí wọ́n ó tún sún bèbè odò Sanjọ́.Àkùkọ kò ì kọ ṣùgbọ́n òyẹ̀ ti là nígbà tí wọ́n mú ọ̀nà pọ̀n. Kí òòrùn tó yọ, wọ́n ti gúnlẹ̀ sí èbúté Táǹńwá níbi tí Sòǹdókò ń gbé.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Èwo ló yàtò?", "a": "Akéwejẹ̀", "b": "Onígègé Àrà", "c": "Olóògùnebi", "d": "Alátùn-únṣe ìlú", "answerKey": "C", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọjá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Èwo ni ó jẹ mọ́ àròkọ ajẹmọ́-ìṣípayá jù?", "a": "Iṣẹ́ dẹ́rẹ́bà dára ju iṣẹ́ káfíntà lọ", "b": "ilé ìgbẹ̀bí àdúgbò mi", "c": "Ìwà ọmọlúwàbí", "d": "Eré orí ìtàgé kan tí mo wò", "answerKey": "C", "context": "wó ṣe pàtàkì, ó ṣe kókó. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé owó kò fẹ́ kí ẹnikẹ́ni dámọ̀ràn kankan lẹ́yìn òun, síbẹ̀ a gbọdọ̀ mọ̀ pé ìráńṣẹ́ ló jẹ́. Kò yẹ kí ó di ọ̀gá fún ẹnikẹ́ni ti Ọba òkè bá fi ṣe búrùjí fún. Láyé àtijọ́, bí ẹnìkan bá ṣiṣẹ́ tó lówó láàárín ẹbí, gbogbo ẹbi ní yóò jàǹfàní rẹ̀. Ìmọ̀ wọn nípa owó pé kò niran, kò jẹ́ kí wọ́n di agbéraga. Bí àwọn bàbá wa ti ní ìtara iṣẹ́ ajé tó, wọn kì í sábà gbọ̀nà àlùmọ̀kọ́rọ́í wá owó. Lóde òní, àwọn ènìyàn ń digunjalẹ̀. wọ́n ń ṣẹ́ṣó, wọ́n ń gbọ́mọ, wọ́n sì ń gbé kokéènì láti lówó.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "[MASK] ni aburo babá Fadékẹ́mi", "a": "Adébáyọ̀", "b": "Àmọ̀pé", "c": "Dékúnlé", "d": "Ọlọ́rọ̀", "answerKey": "A", "context": "Fadékẹ́mi jẹ́ ọmọ òrukàn tí ó sì rẹwà lóbinrin. Láti kékeré ni ó ti ń wẹ̀ nínú ìyà. Ó ń gbé lọ́dọ́ Adébáyọ̀, ábúrò babá rẹ̀, ẹni tí ó fi ìyà pá a lórí dọ́ba, títi tí ó fi sá kúrò níbẹ̀. Ìlú Arárọ̀mí tí ó sá lọ ni ó ti di aláàárù. Ó tún dan iṣẹ́ apọnmità wò, bẹ́ẹ̀ ló tún ṣiṣẹ́ ọmọọdọ̀ lọ́dọ̀ Àmọ̀pé Olóúnjẹ, ṣùgbọ́n kàkà kí ewé àgbọ́n rẹ rọ̀, fíle ló ń le sí i.\n\nÌdí iṣẹ́ bírísopé tí ó tún lọ ṣe ni Dékúnlé ọmọọbá ti pàdé rẹ̀, tí ẹwà rẹ̀ sí wọ̀ ọ́ lójú. Ó bá a sọ̀rọ̀, ọ̀rọ, wọ́n sì wọ̀. Dékúnlé wá bọ́ṣọ ìyà lára rẹ̀, ó sì sọ ọ́ dìyàwó. Báyìí ni orúkọ ro Fadékẹ́mi. Ó di ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó ọlọ́rọ̀ ìlú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní yí nínú ọlá.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Ọ̀rọ̀ mìíràn fún káràkátà ni", "a": "ṣíṣẹ owó", "b": "ẹ̀kọ́ kíkọ́", "c": "àgbẹ̀ ṣíṣe", "d": "kíkọ́ni lẹ́kọ̀ọ́", "answerKey": "A", "context": "Kò-là-kò-sagbe ni Yàyá ọmọ Ògúndìran. Atàpáta-dìde ni ọbàkan rẹ̀, Bísí, ó sì jẹ́ obìnrin. Iṣẹ́ káràkátà ni Yàyá ń ṣe kí ó tó dé ipò tí ó wà yìí. Yàyá ni àbúrò méjì, okùnrin ni àwọn méjèèjì. Àkókò wa ní ilé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ni, èkejì náà wà ní ilé ẹ̀kọ́ girama. \n\nYàyá ni ó ń gbọ́ bùkátà àwọn ọmọ wọ̀nyí láti ìgbà tí ìyàwó wọn ti di olóògbé. Èyí rí bẹ́ẹ̀ nítorí pé gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Ògúndìran wà láyé bí aláìsí ni. Ẹ̀rù yìí pọ̀ fún un láti dá gbé ṣùgbọ́n nítorí pé Ṣọlá jáfáfá lẹ́nu ẹ̀kọ́ rẹ, l̀jọba fi ẹ̀kọ́ dá a lọ́lá láti tẹ̀síwájú sí yunifásítì.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "[MASK] ni Mọ̀gájì", "a": "Adégbọ́lá", "b": "Ṣubúọlá", "c": "Ajírọ́lá", "d": "Adébọ́lá", "answerKey": "B", "context": "Ajírọ́lá àti àwọn àbúrò rẹ̀ pa ẹnu pò láti sé ọjọ́ ìbí fún bàbá wọn. Gbogbo ìlàkàkà bàbá wọn láti ri pé wọ́n di ẹni ayé ń fẹ́ ni ó wú wọn lórí tí wọ́n fi ṣe ẹ̀yẹ yìí fún un. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìránṣẹ́ ni Olóyè Bọ̀sún Owóṣeéní ní ilé iṣẹ́ ìjọba, síbẹ̀ kò fọwọ́ yẹpẹrẹ mú ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ọmọ. Bí ó tí ń ṣiṣẹ́ ọba ní Pápákọ̀ náà ni ó ń dáko tí ó sì tún ń gba àjọ.\n\nÀṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, gbogbo ọmọ rẹ̀ ló rí jájẹ. Ajírọ́lá di dọ́kítà, Adébọ́lá tí ó tẹ̀lé e jẹ́ akọ̀wé àgbà ní báǹki, nígbà tí Mọbọ́lárìn ń ṣe iṣẹ́ lọ́yà, Akin àbíkẹ́yìn rẹ̀ sì jẹ́, oníṣòwò pàtàkì.\nLọ́gán ni ìmúrasílè fún ayẹyẹ bẹ̀rẹ̀. Olóyè Ṣubúọlá, mọ́gàjí agbo-ilé bàbá wọn, ni àwọn ọmọ kọ́kọ́ fi ọ̀rọ̀ ayẹyẹ yìí tó létí. Wọ́n sì tún ránṣẹ́ sí Adégbọ́lá, báálẹ̀ Àkùkọ. Ṣé Balógun ìlú Àkùkọ ni Owóṣeéní. Gbogbo ètò bí ayẹyẹ yóò ṣe kẹ́sẹ̀ járí ni wọ́n farabalẹ̀ ṣe. Wọ́n fìwé ìpè ránṣẹ́ sí ẹbí, ará, àtọ̀rẹ́. Wọ́n sì pín bùkátà ayẹyẹ láàárín ará wọn. Nìgbá tí ó yá, ọjọ́ ayẹyẹ kò. Bí wọ́n tí ń sè ni wọ́n ń sọ̀. Ìdajì nínú àwọn obìnrin ilé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọrin kí ọlọ́jọ́ ìbí lọ́kan-ò-jọ̀kan. \n\nWọ́n wọ aṣọ àǹkárá tí ó jiná, àwọn ọmọ ilé wọ léèsì aláwọ̀ ewé. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé aago méjì ọ̀sán ni ayẹyẹ yóò bẹ̀rẹ̀, agogo mẹ́wáà àárọ̀ ni àwọn tí a fi ìwé pè ti ń dé láti Èkó, ìbàdàn àti Abẹ́òkúta sí Àkùkọ. Tọmọdé tàgbà lo gbédìí fún àwọn ọkọ̀ bọ̀bìnnì bọ̀bìnnì tí ó wọ̀lú lọ́jọ́ náà. Àwọn ọmọ ọlọ́jọ́ ìbí ṣe bẹbẹ. Ọ̀pọ̀ òbí ló sì tipasẹ̀ ayẹyẹ yìí pinnu láti máa ṣojúṣe wọn bó ti tọ́ àti bó ti yẹ sí ọmọ.\n", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jùlọ ni", "a": "Ààbọ̀ ẹ̀kọ́", "b": "Ọmọ bẹẹrẹ", "c": "Àǹfààní ẹ̀kọ́ ìwé", "d": "iṣẹ́ àgbẹ̀ àǹfààní", "answerKey": "C", "context": "Ọmọ bíbí ìlú Béyìíòṣe ni Ìṣọ̀lá. Òun àti àbúrò rẹ̀ Fọláhànmí, nìkan ni Bádéjọ, bàbá wọ́n bí. Àgbẹ̀ oníkòkó aládàáńlá ni Bádéjọ. Bọ́látitó, aya rẹ̀ sì jẹ́ oníṣòwò obì. Bádéjọ kò kàwé ṣùgbọ́n ó pinnu láti tọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ méjéèjì débi tí wọ́n bá lè kàwé dé láyé, nítorí pé ìya àìkàwé jẹ ẹ́ púpọ̀ nídi òwò tí ó ń ṣe.\n\nLẹ́yìn tí Ìṣọ̀lá parí ìwé mẹ́wàá ní ìlú l̀bòdì ni ó gba ìlú Arómisá lọ láti tẹ̀ síwáiú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásitì. Ìlú ọbá ni ó sì ti gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì nínú òfin. Ìṣọ̀lá padà sílúu Béyìíròṣe, ó sì di gbajúgbajà agbẹjọ́rò káàkiri agbègbè náà.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Àwọn tí ó ṣètò ayẹyẹ ni àwọn", "a": "obìnrin", "b": "òbí", "c": "olóyè", "d": "ọmọ", "answerKey": "D", "context": "Ajírọ́lá àti àwọn àbúrò rẹ̀ pa ẹnu pò láti sé ọjọ́ ìbí fún bàbá wọn. Gbogbo ìlàkàkà bàbá wọn láti ri pé wọ́n di ẹni ayé ń fẹ́ ni ó wú wọn lórí tí wọ́n fi ṣe ẹ̀yẹ yìí fún un. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìránṣẹ́ ni Olóyè Bọ̀sún Owóṣeéní ní ilé iṣẹ́ ìjọba, síbẹ̀ kò fọwọ́ yẹpẹrẹ mú ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ọmọ. Bí ó tí ń ṣiṣẹ́ ọba ní Pápákọ̀ náà ni ó ń dáko tí ó sì tún ń gba àjọ.\n\nÀṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, gbogbo ọmọ rẹ̀ ló rí jájẹ. Ajírọ́lá di dọ́kítà, Adébọ́lá tí ó tẹ̀lé e jẹ́ akọ̀wé àgbà ní báǹki, nígbà tí Mọbọ́lárìn ń ṣe iṣẹ́ lọ́yà, Akin àbíkẹ́yìn rẹ̀ sì jẹ́, oníṣòwò pàtàkì.\nLọ́gán ni ìmúrasílè fún ayẹyẹ bẹ̀rẹ̀. Olóyè Ṣubúọlá, mọ́gàjí agbo-ilé bàbá wọn, ni àwọn ọmọ kọ́kọ́ fi ọ̀rọ̀ ayẹyẹ yìí tó létí. Wọ́n sì tún ránṣẹ́ sí Adégbọ́lá, báálẹ̀ Àkùkọ. Ṣé Balógun ìlú Àkùkọ ni Owóṣeéní. Gbogbo ètò bí ayẹyẹ yóò ṣe kẹ́sẹ̀ járí ni wọ́n farabalẹ̀ ṣe. Wọ́n fìwé ìpè ránṣẹ́ sí ẹbí, ará, àtọ̀rẹ́. Wọ́n sì pín bùkátà ayẹyẹ láàárín ará wọn. Nìgbá tí ó yá, ọjọ́ ayẹyẹ kò. Bí wọ́n tí ń sè ni wọ́n ń sọ̀. Ìdajì nínú àwọn obìnrin ilé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọrin kí ọlọ́jọ́ ìbí lọ́kan-ò-jọ̀kan. \n\nWọ́n wọ aṣọ àǹkárá tí ó jiná, àwọn ọmọ ilé wọ léèsì aláwọ̀ ewé. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé aago méjì ọ̀sán ni ayẹyẹ yóò bẹ̀rẹ̀, agogo mẹ́wáà àárọ̀ ni àwọn tí a fi ìwé pè ti ń dé láti Èkó, ìbàdàn àti Abẹ́òkúta sí Àkùkọ. Tọmọdé tàgbà lo gbédìí fún àwọn ọkọ̀ bọ̀bìnnì bọ̀bìnnì tí ó wọ̀lú lọ́jọ́ náà. Àwọn ọmọ ọlọ́jọ́ ìbí ṣe bẹbẹ. Ọ̀pọ̀ òbí ló sì tipasẹ̀ ayẹyẹ yìí pinnu láti máa ṣojúṣe wọn bó ti tọ́ àti bó ti yẹ sí ọmọ.\n", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "\"Gbọ̀ngàn ìlú mi’’ jẹ mọ́ àròkọ [MASK] jù", "a": "aṣàríyànjiyàn", "b": "ajẹmọ́-ìṣípayá", "c": "asọ̀tàn", "d": "aṣàpèjúwe", "answerKey": "D", "context": "Ajírọ́lá àti àwọn àbúrò rẹ̀ pa ẹnu pò láti sé ọjọ́ ìbí fún bàbá wọn. Gbogbo ìlàkàkà bàbá wọn láti ri pé wọ́n di ẹni ayé ń fẹ́ ni ó wú wọn lórí tí wọ́n fi ṣe ẹ̀yẹ yìí fún un. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìránṣẹ́ ni Olóyè Bọ̀sún Owóṣeéní ní ilé iṣẹ́ ìjọba, síbẹ̀ kò fọwọ́ yẹpẹrẹ mú ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ọmọ. Bí ó tí ń ṣiṣẹ́ ọba ní Pápákọ̀ náà ni ó ń dáko tí ó sì tún ń gba àjọ.\n\nÀṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, gbogbo ọmọ rẹ̀ ló rí jájẹ. Ajírọ́lá di dọ́kítà, Adébọ́lá tí ó tẹ̀lé e jẹ́ akọ̀wé àgbà ní báǹki, nígbà tí Mọbọ́lárìn ń ṣe iṣẹ́ lọ́yà, Akin àbíkẹ́yìn rẹ̀ sì jẹ́, oníṣòwò pàtàkì.\nLọ́gán ni ìmúrasílè fún ayẹyẹ bẹ̀rẹ̀. Olóyè Ṣubúọlá, mọ́gàjí agbo-ilé bàbá wọn, ni àwọn ọmọ kọ́kọ́ fi ọ̀rọ̀ ayẹyẹ yìí tó létí. Wọ́n sì tún ránṣẹ́ sí Adégbọ́lá, báálẹ̀ Àkùkọ. Ṣé Balógun ìlú Àkùkọ ni Owóṣeéní. Gbogbo ètò bí ayẹyẹ yóò ṣe kẹ́sẹ̀ járí ni wọ́n farabalẹ̀ ṣe. Wọ́n fìwé ìpè ránṣẹ́ sí ẹbí, ará, àtọ̀rẹ́. Wọ́n sì pín bùkátà ayẹyẹ láàárín ará wọn. Nìgbá tí ó yá, ọjọ́ ayẹyẹ kò. Bí wọ́n tí ń sè ni wọ́n ń sọ̀. Ìdajì nínú àwọn obìnrin ilé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọrin kí ọlọ́jọ́ ìbí lọ́kan-ò-jọ̀kan. \n\nWọ́n wọ aṣọ àǹkárá tí ó jiná, àwọn ọmọ ilé wọ léèsì aláwọ̀ ewé. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé aago méjì ọ̀sán ni ayẹyẹ yóò bẹ̀rẹ̀, agogo mẹ́wáà àárọ̀ ni àwọn tí a fi ìwé pè ti ń dé láti Èkó, ìbàdàn àti Abẹ́òkúta sí Àkùkọ. Tọmọdé tàgbà lo gbédìí fún àwọn ọkọ̀ bọ̀bìnnì bọ̀bìnnì tí ó wọ̀lú lọ́jọ́ náà. Àwọn ọmọ ọlọ́jọ́ ìbí ṣe bẹbẹ. Ọ̀pọ̀ òbí ló sì tipasẹ̀ ayẹyẹ yìí pinnu láti máa ṣojúṣe wọn bó ti tọ́ àti bó ti yẹ sí ọmọ.\n", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Èwo ni ó tàbùkù àṣà ìwọṣọ Yorùbá?", "a": "Sísọ ède Gẹ̀ẹ́sì", "b": "Lílo wíìgi", "c": "Irun dídì okùnrin", "d": "Rírìn ìhòòhò", "answerKey": "D", "context": "Àṣa Yorùbá rẹwà púpọ̀; ó sì jẹ́ ohun ìwúrí fún gbogbo àwọn ọmọ káàárọ̀-ò-jíire láti máa gbé e lárugẹ. Lára àwọn àmúye àṣa Yorùbá ni mímọ Èdè é lò, kí ọmọ Yorùbá sọ̀rọ̀, kí ó sì fa kòmóòkun ọ̀rọ̀ yọ. Ìpèsè oríṣiríṣi oúnjẹ ilẹ̀ Yorùbá, ṣíṣe ara ní ọ̀ṣọ́ àti wíwọ aṣọ tó bá òde mu; gbogbo àwọn ìwọ̀nyí ni Yorùbá fi ń yangàn láwùjọ.\n\nLóde òní, àṣa àjèjì ti gba gbogbo àwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé wọ̀nyí lọ́wọ́ọ púpọ̀ nínú wa. Ède Gẹ̀ẹ́sì ni púpọ̀ ọmọ Yorùbá ń fọ̀. Gbogbo aṣọ tó buyì kẹ́wà tí ó dáàbò bo gbogbo ògo tí Ọlọ́run fún wa ti ń di ohun ìgbàgbé lọ. Ìhòòhò ni àwọn ọmọ mìíràn ń rìn kiri ìlú!\n\nIrun dídì bíi pàtẹ́wọ́, kọjúsọ́kọ, ìpàkọ́ ẹlẹ́dẹ̀, ṣùkú, korobá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ tí ó máa ń móge rẹwà ti fẹ́rẹ̀ di àfìsẹ́hìn téégún aláré ń fiṣọ. Àṣà irun jíjó, gbígbé irun àgùntàn lérí ti gbalẹ̀ kan láàárín ọ̀pọ̀ obìnrin, tí ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin sì ń dirí bíi elégún Ṣángó.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Orí-ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ àròkọ asọ̀tàn jù ni", "a": "Àlá tí ó dèrù bà mí jù lọ", "b": "Iṣẹ́ àgbẹ̀ wù mí jù iṣẹ́ olùkọ́ lo", "c": "irú ilé tí mo fẹ́ kọ́", "d": "Epo pupa", "answerKey": "A", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọiá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Iṣẹ́ wo ni Fadékẹ́mi kọ́kọ́ ṣe?", "a": "Omi pípọntà", "b": "Ọmọọ̀dọ̀", "c": "Bírísopé", "d": "Àárù gbígbà", "answerKey": "D", "context": "Fadékẹ́mi jẹ́ ọmọ òrukàn tí ó sì rẹwà lóbinrin. Láti kékeré ni ó ti ń wẹ̀ nínú ìyà. Ó ń gbé lọ́dọ́ Adébáyọ̀, ábúrò babá rẹ̀, ẹni tí ó fi ìyà pá a lórí dọ́ba, títi tí ó fi sá kúrò níbẹ̀. Ìlú Arárọ̀mí tí ó sá lọ ni ó ti di aláàárù. Ó tún dan iṣẹ́ apọnmità wò, bẹ́ẹ̀ ló tún ṣiṣẹ́ ọmọọdọ̀ lọ́dọ̀ Àmọ̀pé Olóúnjẹ, ṣùgbọ́n kàkà kí ewé àgbọ́n rẹ rọ̀, fíle ló ń le sí i.\n\nÌdí iṣẹ́ bírísopé tí ó tún lọ ṣe ni Dékúnlé ọmọọbá ti pàdé rẹ̀, tí ẹwà rẹ̀ sí wọ̀ ọ́ lójú. Ó bá a sọ̀rọ̀, ọ̀rọ, wọ́n sì wọ̀. Dékúnlé wá bọ́ṣọ ìyà lára rẹ̀, ó sì sọ ọ́ dìyàwó. Báyìí ni orúkọ ro Fadékẹ́mi. Ó di ọ̀kan nínú àwọn ìyàwó ọlọ́rọ̀ ìlú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní yí nínú ọlá.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Irú ènìyàn wó ni ẹni tó ń sọ̀rọ̀?", "a": "Onífàyàwó", "b": "Adáhunṣe", "c": "Oníṣòwò", "d": "Ọba", "answerKey": "D", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọjá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Àkọ́lé tí ó bá àyọkà yìí mu jù ni [MASK]", "a": "Àwọn adigunjalè", "b": "Owó níní", "c": "Àǹfààní olówó", "d": "gbígbé kokéènì", "answerKey": "B", "context": "wó ṣe pàtàkì, ó ṣe kókó. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé owó kò fẹ́ kí ẹnikẹ́ni dámọ̀ràn kankan lẹ́yìn òun, síbẹ̀ a gbọdọ̀ mọ̀ pé ìráńṣẹ́ ló jẹ́. Kò yẹ kí ó di ọ̀gá fún ẹnikẹ́ni ti Ọba òkè bá fi ṣe búrùjí fún. Láyé àtijọ́, bí ẹnìkan bá ṣiṣẹ́ tó lówó láàárín ẹbí, gbogbo ẹbi ní yóò jàǹfàní rẹ̀. Ìmọ̀ wọn nípa owó pé kò niran, kò jẹ́ kí wọ́n di agbéraga. Bí àwọn bàbá wa ti ní ìtara iṣẹ́ ajé tó, wọn kì í sábà gbọ̀nà àlùmọ̀kọ́rọ́í wá owó. Lóde òní, àwọn ènìyàn ń digunjalẹ̀. wọ́n ń ṣẹ́ṣó, wọ́n ń gbọ́mọ, wọ́n sì ń gbé kokéènì láti lówó.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Kíni ìtumọ̀ ‘rú fín-in'?", "a": "Fárígá", "b": "Gbìyànjú", "c": "Bínú", "d": "Borí", "answerKey": "B", "context": "Bí àlá ló ń ṣe Bọ́ládé nígbà tí èsì ìbò tí àwọn ará Àlàdé àti agbègbè rẹ̀ dì jáde pé òun ni wọ́n dìbò yàn gẹ́gẹ́ bí alága ìjọba ìbíla Ayédé. Èsì ìbò yìí ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ lẹ́nu nítorí kò ṣẹni tó tilẹ̀ rò pé ó lè rú-fin-in nítorí pé àgbẹ̀ paraku ni, kò lówó lọ́wọ́ àti pé àwọn lóókọlóókọ nílùú bí Olóyè\nAgboadé, Dọ́kítà Ọláìyá, Lọ́yà ìbídàpọ̀ àti Arábinin Sáúdátù tíí ṣe oníṣòwò pàtàkì ló bá a fi iga gbága.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Jẹnẹra Àyìnlá ni ó", "a": "kí ọba", "b": "gun ẹṣin", "c": "gba ẹ̀bùn", "d": "jáde jó", "answerKey": "B", "context": "Ohun gbogbo ló ni àsìkò tirẹ̀. Nígbà tí àsìkò tó fún àwọn ẹgbẹẹgbẹ́ wọ̀nyí láti jó kí ọba ni a ṣẹ̀ṣẹ̀ tó wá ríran wò. Ṣé ní ti ẹgbẹ́, wọ́n pọ̀ lọ súà bí ọlá Ọlọ́run: Ìdáǹdè, Ọmọladé, Òmìnira, Ọmọ́yèiú, Bọ́bakẹyẹ, Ajagungbadé, Ọbatèkóbọ̀, Ọbaníbàṣírí, Bọ́bagúntẹ̀, àti bẹ́è bẹ́ẹ̀ lọ.\n\nTí a bá ní kí á máa to àwọn orúkọ ẹgbẹ́ wọ̀nyí bí wọ́n ṣe pọ̀ tó, yóò gba odindin ojú-ìwé méjì níbi tí wọ́n pọ̀ dé. Bí oníkàlùkù wọn ti ń jáde lọ síwájú kábíyèsí pẹ̀lú ẹ̀bùn wọn lọ́wọ́ ni àwọn òṣèré wọn ń lù tẹ̀lé wọn lẹ́yìn. Músílíù ọmọ Hárúnà Ìṣọ̀lá kọ kísà lórin. Eléré ìbílẹ̀ kan tí wọn ń pè ní Ìdàgẹ̀rẹ̀ náà ko ségè lórin. Orí ẹṣin funfun ni Jẹnẹra Àyìnlá wà tó ń kọrin fún ẹgbẹ́ Ìdáǹdè.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Ta ni akéwì sọ pé ó máa gbowó ẹ̀yìn?", "a": "Olùkọ́", "b": "Kólékóle", "c": "Ọlọ́pàá", "d": "Adájọ́", "answerKey": "C", "context": "Bó o bá réèyan tó fówó láfẹ̀ẹ́jù\nỌgbọ́n inú ni kó o fi máa bá a lò\nKò síwà búburú kan tí irú wọn kò lè wù\nBá a fiwọ́n sípò iyì, wọn kò jẹ́ ṣòótọ́ \nBí wọ́n jọ́lọ́paá, wọn a gbowó ẹ̀yìn \nBí wọ́n jádájọ́, wọn á gbẹ́bi fáláre \nBí wọ́n jólùkọ́, wọn á fohun burúkú kọ́mọ \nBí wọ́n jójìíṣẹ́ Ọlọ́run, wọn á ṣi ọ̀pọ̀ lọ́nà\nWò wọ́n léèkan kó o kọjú sí ibi ò ń lọ \nMo bẹ̀ ọ́, má tilẹ̀ fara wé wọn \nÌfẹ́-owó ṣáà ni gbòǹgbò ẹ̀ṣẹ̀ \nAláṣọ dúdú tó ń rìn kiri lóru\nÀwọn tí kìí fojú róhun olóhun\nAlágbàtà tó pa ṣíṣi tó pè é ní tọ́rọ́ fólówó\nẸni tó ń bàṣírí apààyàn àti kólékólé\nẸyí tí ó ń ṣe fàyàwọ́, èyí tí ń tọwọ́ bàpò alápò\nÈyí tó ń parọ́ fún ni bí ẹni láyin\nỌ̀nà àtijí ohun olóhun mọ́ tiwọn ni wọ́n ń ṣe kiri!", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Orí-ọ̀rọ̀ tí ó bá àrọ̀kọ oníròyìn mu jù ni", "a": "Awo ifá sàn ju awo eégún", "b": "Epo ìsebẹ̀", "c": "Ọjọ́ kan tí ayé sú mi", "d": "Ayé òde-òní", "answerKey": "C", "context": "\"Orí ọ̀kẹ́rẹ́ koko láwo, báa wi fọ́mọ ẹni a gbọ́\", èyí ni gbólóhùn tí ó jáde lẹ́nu Àkàndé tí i ṣe bàbá Àlàó, bí ọmọ rẹ̀ tí ń japoró ikú lóríbùsùn ní ilé-Ìwòsàn Márapé ní Dòho.\n\nÀlàó jẹ́ ọmọ ìlú Òkè-Ẹgàn. Láti kékeré ni l̀yápé, l̀yá Àlàó ti bà á jẹ́, nítorí pé ó jẹ́ ògúnná kanṣoṣo tí ó ní. Gbogbo akitiyan Àkàndé ní títọ́ Àlàó sọ́nà ló já sí pàbó. Àlàó jayé alákátá, ó gbé ìwà ìṣekúṣe wọ̀ bí ẹ̀wù. Bí dúdú ti ń wá, ni pupa ń wá sọ́ọ̀dẹ̀ rẹ̀, kódà ó fẹ́rè lè máa gbé wèrè ní àgbésùn. Àyẹ̀wò tí ó lọ ṣe ni ó fi hàn pé ó ti kó àrùn-kògbóògùn.\n\nÀlàó gbà pé ikú yá ju ẹ̀sín, èyí ni ó mú un gbé májèlé jẹ, èyí tí ó sọ ọ́ di èró ilé-ìwòsàn.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "\"Kàyééfì túmọ̀ sí", "a": "ìlára", "b": "ìyọ̀nda", "c": "ìyàlẹ́nu", "d": "", "answerKey": "C", "context": "Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé Àṣàké ni ààyò Délé. Ọlọ́run kò tètè yọ̀nda. ọmọ fún un. l̀yáalé rẹ̀, Àjọ́kẹ́ ti bí ìsun, l̀yàwó tí Déié fẹ́ tẹ̀lé e, Àníkẹ́, náà ti bí ìwàlè. Àwọn méjèèjì a sì máa wo Àṣàké bi ọlọ́wọ́-ṣíbí tó kàn wá bá ọkọ wọn jẹun lásán. Gbogbo ìgbà ni Délé máa ń gbàdúrà kí Ọlọ́run tètè dá Àṣàkẹ́ lóhùn. Ìparí oṣù tí iṣé pàjáwìrì gbé Délé lọ sí Òkè-òkun ni Àṣàkẹ́ déédéé rí i pé òun ti fẹ́ra kù! Wéré lo tẹ ọkọ rẹ̀ láago láti fún un ní ìròyin ayọ̀ náà. Kàyéfí ni ó jẹ́ fún àwọn orogún rẹ láti rí i ní ipò tó wa, wọ́n sì ń fojú ìlara wò ó. Oṣù mẹ́fà ni Délé lò lẹ́yìn odi kí ó tó padà wá sílé. Oṣù kejì tó dé ni Àṣàkẹ́ bímọ, ọmọ náà si jọ Délé bí ìmumu. Ó sọ ọ́ ní Ọmọniyì. Àṣàkẹ́' sọ, ọ́ ní Olúwajùwá.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Ọmọ ìbídàpọ̀ ni ó joyè", "a": "Akéwejẹ̀", "b": "ọ̀tún Bàbálájé", "c": "Alátùn-únṣe", "d": "Yèyé Oge", "answerKey": "B", "context": "Mo kí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn mi tí ẹ péjọ̀ síbí lónìí. Inú mi sì dùn jọjọ dé ibi pé bí ènìyàn bá gẹṣin nínú mi olúwarẹ̀ kò ní kọsè. A dájọ́, ọjọ́ pé, a dá ìgbà, ìgbà sì kò. Mo sì dúpẹ́ Iọ́wọ́ Adẹ́dàá nítorí èyí ṣojú wa ná.\n\nNí ìdunta ni irú ayẹyẹ, ìfinijoyè báyìí wáyé gbẹ̀yìn ní ìlú wa yìí. Nígbà náà lọ́hùn-ún, ènìyàn mẹ́ta péré ni mo fi oyè dá lọ́lá, ṣùgbọ́n lónìí, ènìyàn mẹ́jọ ni n ó já ewé oyè lé lóri - ọkùnrin márùn-ún àtí obìnrin mẹ́ta - fún iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe fún ìdàgbàsókè ìlú yìí. Mo sì fẹ́ kí eléyìí jẹ́ àwòkọ́ṣe fún ẹ̀yin tó nífọ̀n tó tún ní èékánná ní ìlú yìí. Ògún ilé ni mo fé kí ẹ kọ́kọ́ máa bẹ̀ kí ẹ tó bẹ tìta, kí ẹ sì jáwọ́ nínú ìwà aláǹgbàá orí èṣù àti ìwà amúnibúni ẹran-ìbíyẹ. Ẹ jáwọ́ nínú ìwà fàyàwọ́ àti òògùn olóró gbígbé kí ẹ má baà ta epo sí àlà orúkọ ìlú wa yìí mọ́. Mo sọ èyí kí ọ̀rọ̀ yín má baà dà bí i ti Adélọjá àti Ọláòṣéépín. Ẹ̀wọ̀n ogún ọdún ni ẹni àkọ́kọ́ tí i ṣe ọmo ìlú Ayépé ń ṣe lọ́wọ́ báyìí fún fàyàwọ́ nígbà tí ẹnìkejì fi ẹ̀yìn tàgbá ní Sòǹdókò fún igbó gbíngbìn.\n\nỌlátẹ́jú tí i ṣe ọ̀gá àgbà ní ilé ìfowópamọ́ òlóògunebí ni yóò jẹ oyè Bàbálájé ìlú wa yìí. Ṣé ẹ kò gbàgbé ilé iṣẹ́ ńlá tó dá sílẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ìlú yìí tí ń ṣiṣẹ́? Oyè Ọ̀tún Bàbálájé ni ti ọ̀rẹ́dẹbí rẹ̀ Adédùntán. Ẹ má gbàgbé pé Ọ̀rẹ́ kòríkòsùn niwọ́n àti pé Adédùntán tí i ṣe oníṣòwò pàtàkì ti ṣètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga tó kù díẹ̀ káà-tó fún ní ìlú yìí bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé Ìbídàpọ̀ ni ó ti wá. Ọládélé tí ṣe ọ̀gá lẹ́nu iṣẹ́ ọba tí ó ran àwọn ọmọ bíbí ìlú yìí lọ́wọ́ láti rí iṣẹ́ ọba ni yóò jẹ oyè Alátùn-únṣe ìlú nígbà tí oníṣègùn Babátúndé yóò di Agbáṣàga. Káńsílọ̀ ètò ẹ̀kó ìjọba ìbílẹ̀ yìí, ọ̀gbẹ́ni Tàlàbí di Olóyè Akéwejẹ̀. Arábìnrin Bísí, aya Adélọdún ni yóò dipò olóogbé Súọlá aya Tẹ̀là gẹ́gẹ́ bí l̀yálájé. Ṣèbí gbogbo wa ni a mọ̀ ón sí gbajúmọ̀ òǹtajà ní ìlú Kánnádopó. llé ìtajà tí ó kọ́ sílẹ̀ wa yìí àti agbègbè rẹ̀ jẹ́ méwàá. Màmá wa Adúlójú ni n ó já ewé oyè Yèyé Ọba lé lórí lónìí, nígbà tí arábìnrin Yétúndé aya Babalọlá, yóò jẹ oyè Onígègé Àrà ìlú Ajégúnlẹ̀ wa yìí láti òní.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Kí ni àyọrísí ìwà tí Àlàó hù nínú àyọkà yìí?", "a": "Ó ń gbé wèrè ṣàgbésùn", "b": "Ó pa òwe \"ikú yá ju ẹ̀sín", "c": "Ó kó àrùn-kògbóògùn", "d": "Ó di ọmọ ìlú Òkè-Ẹgàn", "answerKey": "C", "context": "\"Orí ọ̀kẹ́rẹ́ koko láwo, báa wi fọ́mọ ẹni a gbọ́\", èyí ni gbólóhùn tí ó jáde lẹ́nu Àkàndé tí i ṣe bàbá Àlàó, bí ọmọ rẹ̀ tí ń japoró ikú lóríbùsùn ní ilé-Ìwòsàn Márapé ní Dòho.\n\nÀlàó jẹ́ ọmọ ìlú Òkè-Ẹgàn. Láti kékeré ni l̀yápé, l̀yá Àlàó ti bà á jẹ́, nítorí pé ó jẹ́ ògúnná kanṣoṣo tí ó ní. Gbogbo akitiyan Àkàndé ní títọ́ Àlàó sọ́nà ló já sí pàbó. Àlàó jayé alákátá, ó gbé ìwà ìṣekúṣe wọ̀ bí ẹ̀wù. Bí dúdú ti ń wá, ni pupa ń wá sọ́ọ̀dẹ̀ rẹ̀, kódà ó fẹ́rè lè máa gbé wèrè ní àgbésùn. Àyẹ̀wò tí ó lọ ṣe ni ó fi hàn pé ó ti kó àrùn-kògbóògùn.\n\nÀlàó gbà pé ikú yá ju ẹ̀sín, èyí ni ó mú un gbé májèlé jẹ, èyí tí ó sọ ọ́ di èró ilé-ìwòsàn.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Ta ni 'amọniṣeni?", "a": "Sakasaka", "b": "Kàsúmù", "c": "Àmọ̀dá", "d": "Ìgárá", "answerKey": "C", "context": "Ilẹ̀ ọlọ́ràá tí Ẹlẹ́dàá fi jìnkí àwọn ará abúlé Aṣaka ló sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn di ẹni tí ajé ń bá jẹun. Ṣakaṣaka ni orúkọ baba ńlá wọn tí ó ti ìlú Aperin wa, lẹ́yìn tí ó ti kọ́kọ́ tẹ̀dó sí abúlé Ọmọ́là.\nIlẹ̀ abà yìí tí ó dára jẹ́ kí nǹkan oko wọ́n máa ṣe dáradára, ṣùgbọ́n àwọn olè kò jẹ́ kí wọn ó ri owó tí wọ́n pa ná. Àwọn ará abà yìí náà kò fọwọ́ lẹ́rán, àwọn géndé abà yìí pín ara wọn sí ẹgbẹẹgbẹ́ ojú-lalákan-fi-í -ṣọ́rí. Wọn a máa jáde ní òru, wọn a sì máa ṣọ́ ìlú.\n\nÀṣé Àmọ̀dá ni kòkòrò tí ó ń jẹ̀fọ́. Ìlú Ìlokọ́ ló ti sá wálé. Oko kòkó Kásúmù, baba rẹ̀ tí ó sì sọ pé òún wá jókòó ti férè run tán. Kò wá sí ẹni tí ó torí éyí fura sí i. Kúrá kìí lọ sí oko olè, àmó òun ló máa ń júwe ilé ẹni tí ó bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ta irè-oko fún àwọn apamọlẹ́kún-jayé. Ọjọ́ gbogbo ni tolè, ọjọ́ kan ṣoṣo ni tolóhun. Ní òru ọjọ́ kan ọwọ́ tẹ díẹ̀ lára àwọn ìgárá náà, wọ́n sì jẹ́wọ́ pé Àmọ̀dá jẹ́ ọ̀kan lára igi-lẹ́yìn-ọgbà àwọn. Lọ́gán ni wọ́n lọ mú u, tí wọ́n sì fa òun àti àwọn ọmọ-iṣẹ́ rẹ̀ lé ìjọba lọ́wọ́.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" }, { "question": "Ta ni Ọbàkan Yàyá?", "a": "Olóògbé", "b": "Ògúndìran", "c": "Ṣọlá", "d": "Bísí", "answerKey": "D", "context": "Kò-là-kò-sagbe ni Yàyá ọmọ Ògúndìran. Atàpáta-dìde ni ọbàkan rẹ̀, Bísí, ó sì jẹ́ obìnrin. Iṣẹ́ káràkátà ni Yàyá ń ṣe kí ó tó dé ipò tí ó wà yìí. Yàyá ni àbúrò méjì, okùnrin ni àwọn méjèèjì. Àkókò wa ní ilé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ni, èkejì náà wà ní ilé ẹ̀kọ́ girama. \n\nYàyá ni ó ń gbọ́ bùkátà àwọn ọmọ wọ̀nyí láti ìgbà tí ìyàwó wọn ti di olóògbé. Èyí rí bẹ́ẹ̀ nítorí pé gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Ògúndìran wà láyé bí aláìsí ni. Ẹ̀rù yìí pọ̀ fún un láti dá gbé ṣùgbọ́n nítorí pé Ṣọlá jáfáfá lẹ́nu ẹ̀kọ́ rẹ, l̀jọba fi ẹ̀kọ́ dá a lọ́lá láti tẹ̀síwájú sí yunifásítì.", "grade": "SS3", "preamble": "", "category": "Reading comprehension" } ]